POST Taanu Re (Lyrics) by Toyin Ogbinoluwa

posted by vicky684 about 12 months ago
Taanu Re (Lyrics) by Toyin Ogbinoluwa

Content


Song Lyrics: Taanu Re
.
Iba mase taanu Re
Mba ma ti wonu le
Iba mase taanu Re
Mba ma ti wonu le

Iba mase taanu Re
Mba ma ti wonu le
Iba mase taanu Re
Mba ma ti wonu le

Aanu toga mori gba
EMi o mo adura n gba
Iwa mimo mi o kun nu igba
Tori mori mori aanu gba

Iba mase taanu Re
Mba ma ti wonu le
Iba mase taanu Re
Mba ma ti wonu le

Gbengbeleku to nda nibi towu
Mo ki O oooo O wo sokoto..
kembe Rebi ija o 2x
Mo ki Eni ti okun ri ti o sa!
Mo ki O Eni ti Jodani ri to pada sehin
Mo wari fun Eniti oke nla ri tofo bi agbo
Mo se sadankata fEni ti oke kekeke ri ti o le duro
Modupe fun aanu ti mo ri gba.

Mba ma ti wonu le

Ibamase taanu Re
Mba ma ti wonu ile

Ibamase teje Re o Jesu
Mba ma ti wonu ile

Olurapada aye mi O se
Mba ma ti wonu ile

Ile o ga ju mi Iwo Iwo mani
Mba ma ti wonu ile

Wonu Ile!
About Autor

vicky684


I am Victor UC popularly known as "Mr Victor Vlogs", I am a blogger, Content creator, web developer, etc.

0 Comments

......

Drop your comment:Related Post

Do you have an Album, Videos or single tracks to upload on gospelflavour.com?

Feel free to click the upload button